Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 15:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí àwọn aláìkọlà kí ó lè yin Ọlọ́run lógo nítorí àánú rẹ̀; gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ pé:“Nítorí èyí ni èmi ó ṣe yìn ọ́ láàrin àwọn aláìkọlà,Èmi ó sì kọrin sí orúkọ rẹ.”

Ka pipe ipin Róòmù 15

Wo Róòmù 15:9 ni o tọ