Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 15:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmí rọ̀ yín, ẹ̀yin ará, nítorí Olúwa wa Jésù Kírísítì, àti nítorí ìfẹ́ Ẹ̀mí, kí ẹ̀yin kí ó kún mi láti bá mi làkàkà nínú àdúrà yín sí Ọlọ́run fùn mi.

Ka pipe ipin Róòmù 15

Wo Róòmù 15:30 ni o tọ