Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 15:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ti fi ìgboyà kọ̀wé sí yín lórí àwọn kókó ọ̀rọ̀ kan, bí ẹni ti ń rán yín létí àwọn kókó ọ̀rọ̀ náà, nítorí oore-ọ̀fẹ́ tí a ti fifún mi láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run

Ka pipe ipin Róòmù 15

Wo Róòmù 15:15 ni o tọ