Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 11:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun kan náà yìí ni Dáfídì ọba sọ̀rọ̀ rẹ̀ wí pé:“Kí oúnjẹ àti àwọn nǹkan mèremère wọn tàn wọ́n,láti rò pé wọ́n rí ojú rere Ọlọ́run.Jẹ́ kí àwọn nǹkan wọ̀nyí padà dojú ìjà kọ wọ́n,kí a bá à lè fi òtítọ́ wó wọn túútúú.

Ka pipe ipin Róòmù 11

Wo Róòmù 11:9 ni o tọ