Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 11:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣebí ẹ̀yin náà mọ̀ pé Ọlọ́run ti yà mi sọ́tọ̀ gẹ́gẹ́ bí ajíyìnrere fún àwọn aláìkọlà. Mo ń tẹnumọ́ ọn gidigidi mo sì ń rán àwọn Júù létí nípa rẹ̀ nígbákùúgbà tí ààyè bá wà.

Ka pipe ipin Róòmù 11

Wo Róòmù 11:13 ni o tọ