Ṣùgbọ́n mo ní, wọn kò ha gbọ́ bí? Bẹ́ẹ̀ ni nítòótọ́:“Ohùn wọn jáde lọ sí gbogbo ilẹ̀,àti ọ̀rọ̀ wọn sí òpin ayé.”