Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 9:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì rìn yí gbogbo ìlú ńlá àti ìletò ká, ó ń kọ́ni nínú sínágọ́gù wọn, ó sì ń wàásù ìyìn rere ìjọba, ó sì ń ṣe ìwòsàn àrùn àti gbogbo àìsàn ní ara àwọn ènìyàn.

Ka pipe ipin Mátíù 9

Wo Mátíù 9:35 ni o tọ