Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 8:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni gbogbo ará ìlú náà sì jáde wá í pàdé Jésù. Nígbà tí wọ́n sì rí i, wọ́n bẹ̀ ẹ́, kí ó lọ kúrò ní agbégbé wọn.

Ka pipe ipin Mátíù 8

Wo Mátíù 8:34 ni o tọ