Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 3:15-17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

15. Jésù sì dáhùn pé, “Jọ̀wọ́ rẹ̀ bẹ́ẹ̀ náà, ní torí bẹ́ẹ̀ ni ó yẹ fún wa láti mú gbogbo òdodo ṣẹ.” Bẹ́ẹ̀ ni Jòhánù gbà, ó sì ṣe ìbamitíìsì fún un.

16. Bí a si tí ṣe ìtẹ̀bọmi fún Jésù tán, Ó jáde láti inú omi. Ní àkókò náà ọ̀run sí sílẹ̀, Ó sì rí Ẹ̀mí Ọlọ́run ń sọ̀ kalẹ̀ bí àdàbà àti bi mọ̀nàmọ́ná sórí rẹ̀.

17. Ohùn kan láti ọ̀run sì wí pé, “Èyí ni ọmọ mi, ẹni ti mo fẹ́ràn, ẹni tí inú mi dùn sí gidigidi.”

Ka pipe ipin Mátíù 3