Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 3:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí a si tí ṣe ìtẹ̀bọmi fún Jésù tán, Ó jáde láti inú omi. Ní àkókò náà ọ̀run sí sílẹ̀, Ó sì rí Ẹ̀mí Ọlọ́run ń sọ̀ kalẹ̀ bí àdàbà àti bi mọ̀nàmọ́ná sórí rẹ̀.

Ka pipe ipin Mátíù 3

Wo Mátíù 3:16 ni o tọ