Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 25:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo wà ní ìhòòhò, ẹ̀yin sì daṣọ bò mí. Nígbà tí mo ṣe àìsàn ẹ ṣe ìtójú mi, àti ìgbà tí mo wà ní ọgbà ẹ̀wọ̀n ẹ̀yín bẹ̀ mí wò.’

Ka pipe ipin Mátíù 25

Wo Mátíù 25:36 ni o tọ