Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 25:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ebí pa mi, ẹ̀yin sì fún mi ní oúnjẹ, òrùngbẹ gbẹ mí, ẹyin sì fún mi ní omi. Mo jẹ́ àlejò, ẹ̀yin sì pè mí sínú ilé yín.

Ka pipe ipin Mátíù 25

Wo Mátíù 25:35 ni o tọ