Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 21:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀pọ̀ ènìyàn ń lọ níwájú rẹ̀ àti lẹ́yìn rẹ̀ pẹ̀lú ń kígbe pé,“Hòsánà fún ọmọ Dáfídì!”“Olùbùkún ni fún ẹni tí ó ń bọ̀ ní orúkọ Olúwa!”“Hòsánà ní ibi gíga jùlọ!”

Ka pipe ipin Mátíù 21

Wo Mátíù 21:9 ni o tọ