Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 21:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ sọ fún ọmọbìnrin Síónì pé,‘Wò ó, ọba rẹ ń bọ̀ wá sí ọ̀dọ̀ rẹ,ní ìrẹ̀lẹ̀, ó ń gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,àti lórí ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.’ ”

Ka pipe ipin Mátíù 21

Wo Mátíù 21:5 ni o tọ