Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 21:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́ẹ̀kejì, ó rán àwọn ìránṣẹ́ tí ó pọ̀ ju ti ìṣaájú sí wọn. Wọ́n sì tún ṣe bí ti àkọ́kọ́ sí àwọn wọ̀nyí pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Mátíù 21

Wo Mátíù 21:36 ni o tọ