Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 21:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbo ni ìtẹ̀bọmi Jóhànù ti wa? Láti ọ̀run wá ni, tàbí láti ọ̀dọ̀ ènìyàn.”Wọ́n sì bá ara wọn gbèrò pé, “Bí àwa bá wí pé láti ọ̀run wá ni, òun yóò wí fún wa pé, ‘È é ha ti ṣe tí ẹ̀yin kò fi gbà á gbọ́?’

Ka pipe ipin Mátíù 21

Wo Mátíù 21:25 ni o tọ