Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 21:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì wọ inú tẹ́ḿpì Ọlọ́run. Ó sì lé àwọn ti ń tà àti àwọn ń rà níbẹ̀ jáde. Ó yí tábìlì àwọn onípàsípààrọ̀ owó dànù, àti tábìlì àwọn tí ó ń ta ẹyẹlẹ́.

Ka pipe ipin Mátíù 21

Wo Mátíù 21:12 ni o tọ