Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 20:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Jésù àti àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ ti ń fi ìlú Jẹ́ríkò sílẹ̀, ọ̀pọ̀ ènìyàn sì wọ́ tẹ̀lé e lẹ́yìn.

Ka pipe ipin Mátíù 20

Wo Mátíù 20:29 ni o tọ