Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 2:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n si béèrè pé, “Níbo ni ẹni náà tí a bí tí í ṣe ọba àwọn Júù wà? Àwa ti rí ìràwọ̀ rẹ̀ ní ìlà-oòrun, a sì wá láti foríbalẹ̀ fún un.”

Ka pipe ipin Mátíù 2

Wo Mátíù 2:2 ni o tọ