Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 2:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn ìgbà tí a bí Jésù ní Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ti Jùdíà, ni àkókò ọba Hẹ́rọ́dù, àwọn amoye ti ìlà-oòrùn wá sí Jerúsálémù.

Ka pipe ipin Mátíù 2

Wo Mátíù 2:1 ni o tọ