Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 19:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Lẹ́yìn tí Jésù ti parí ọ̀rọ̀ yìí, ó kúrò ní Gálílì. Ó sì yípo padà sí Jùdíà, ó gba ìhà kejì odò Jọ́dánì.

2. Ọ̀pọ̀ ènìyàn sì ń tọ̀ ọ́ lẹ́yìn, ó sì mú wọn láradá níbẹ̀.

Ka pipe ipin Mátíù 19