Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 19:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn tí Jésù ti parí ọ̀rọ̀ yìí, ó kúrò ní Gálílì. Ó sì yípo padà sí Jùdíà, ó gba ìhà kejì odò Jọ́dánì.

Ka pipe ipin Mátíù 19

Wo Mátíù 19:1 ni o tọ