Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 16:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìran búburú aláìgbàgbọ́ yìí ń béèrè àmì àjèjì mélòó kàn ni ojú sánmọ̀, ṣùgbọ́n a kí yóò fún ẹnìkan kan ní àmì bí kò ṣe àmì Jónà.” Nígbà náà ni Jésù fi wọ́n sílẹ̀, ó sì bá tirẹ̀ lọ.

Ka pipe ipin Mátíù 16

Wo Mátíù 16:4 ni o tọ