Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 16:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù pa ojú dà, ó sì wí fún Pétérú pé, “Kúrò lẹ́yìn mi, Sàtáni! Ohun ìkọ̀ṣẹ̀ ni ìwọ jẹ́ fún mi; ìwọ kò ro ohun tí i se ti Ọlọ́run, bí kò se èyí ti se ti ènìyàn.”

Ka pipe ipin Mátíù 16

Wo Mátíù 16:23 ni o tọ