Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 16:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ìgbà yìí lọ, Jésù bẹ̀rẹ̀ sí iṣàlàyé fún àwọn ọmọ-ẹ̀yin rẹ̀ kedere nípa lílọ sí Jerúsálémù láti jẹ ọ̀pọ̀ ìyà lọ́wọ́ àwọn, olórí àwọn àlùfáà àti àwọn olùkọ́ òfin, pé wọn yóò pa òun, àti pé òun yóò jí dìde sí ààyè ní ọjọ́ kẹ́ta.

Ka pipe ipin Mátíù 16

Wo Mátíù 16:21 ni o tọ