Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 15:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnú ya ọ̀pọ̀ ènìyàn nígbà tí wọ́n rí àwọn odi tó ń sọ̀rọ̀, amúkùn-ún tó di alára pípé, arọ tí ó ń rìn àti àwọn afọ́jú tí ó ríran. Wọ́n sì ń fi ìyìn fún Ọlọ́run Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Mátíù 15

Wo Mátíù 15:31 ni o tọ