Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 13:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí àyà àwọn ènìyàn yìí sébọ́etí wọn sì wúwo láti gbọ́ojú wọn ni wọ́n sì dìnítorí kí àwọn má ba à fi ojú wọn ríkí wọ́n má ba à fi ètí wọn gbọ́kí wọn má ba à fi àyà wọn mọ̀ òge,kí wọn má ba à yí padà, kí èmi ba à le mú wọn lára dá.’

Ka pipe ipin Mátíù 13

Wo Mátíù 13:15 ni o tọ