Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 13:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sí ara wọn ni a ti mú àṣọtẹ́lẹ̀ wòlíì Àìsáyà ṣẹ:“ ‘Ní gbígbọ́ ẹ̀yin yóò gbọ́ ṣùgbọn kì yóò sì yé yín;ní rírí ẹ̀yin yóò rí, ṣùgbọ́n ẹ̀yin kì yóò sì mòye.

Ka pipe ipin Mátíù 13

Wo Mátíù 13:14 ni o tọ