Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 12:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó dá wọn lóhùn pé, “Bí ó bá jẹ́ wí pé bí ẹnikẹ́ni nínú yín bá ní àgùntàn kan ṣoṣo, tí ó sì bọ́ sínú kòtò ní ọjọ́ ìsinmi, tí kì yóò dì í mú, kí ó sì fà á jáde.

Ka pipe ipin Mátíù 12

Wo Mátíù 12:11 ni o tọ