Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 12:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ọkùnrin kan tí ọwọ́ rẹ̀ kan rọ wà níbẹ̀. Wọ́n ń wá ọ̀nà láti fi ẹ̀sùn kan Jésù, wọ́n béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé, “Ǹjẹ́ ó tọ́ láti mú ènìyàn láradá ní ọjọ́ ìsinmi?”

Ka pipe ipin Mátíù 12

Wo Mátíù 12:10 ni o tọ