Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 10:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ológoṣẹ́ méjì kọ́ ni à ń tà ní owó idẹ wẹ́wẹ́ kan? Ṣíbẹ̀ kò sí ọ̀kan nínú wọn tí yóò ṣubú lulẹ̀ lẹ́yìn Baba yin.

Ka pipe ipin Mátíù 10

Wo Mátíù 10:29 ni o tọ