Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 10:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí náà, ẹ má ṣe bẹ̀rù wọn, nítorí kò sí ohun to bò tí kò níí fara hàn, tàbí ohun tó wà ní ìkọ̀kọ̀ tí a kò ní mọ̀ ni gbangba.

Ka pipe ipin Mátíù 10

Wo Mátíù 10:26 ni o tọ