Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 10:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìlúkílùú tàbí ìletòkíletò tí ẹ̀yin bá wọ̀, ẹ wá ẹni ti ó bá yẹ níbẹ̀ rí, níbẹ̀ ni kí ẹ sì gbé nínú ilé rẹ̀ títítí ẹ̀yin yóò fi kúrò níbẹ̀.

Ka pipe ipin Mátíù 10

Wo Mátíù 10:11 ni o tọ