Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 10:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ méjìlá sí ọ̀dọ̀; ó fún wọn ní àṣẹ láti lé ẹ̀mí àìmọ́ jáde àti láti ṣe ìwòsàn àrùn àti àìsàn gbogbo.

Ka pipe ipin Mátíù 10

Wo Mátíù 10:1 ni o tọ