Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 1:23-25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

23. “Wúndíá kan yóò lóyún, yóò sì bí ọmọkùnrin kan, a ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní ‘Èmánúẹ́lì,’ ” èyí tí ó túmọ̀ sí, “Ọlọ́run wà pẹ̀lú wa.”

24. Nígbà tí Jósẹ́fù jí lójú oorun rẹ̀, òun ṣe gẹ́gẹ́ bí ańgẹ́lì Olúwa ti pàṣẹ fún un. Ó mú Màríà wá sílé rẹ̀ ní aya.

25. Ṣùgbọ́n òun kò mọ̀ ọ́n títítí ó fi bí ọmọkùnrin, òun sì sọ orúkọ rẹ̀ ní Jésù.

Ka pipe ipin Mátíù 1