Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 1:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wúndíá kan yóò lóyún, yóò sì bí ọmọkùnrin kan, a ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní ‘Èmánúẹ́lì,’ ” èyí tí ó túmọ̀ sí, “Ọlọ́run wà pẹ̀lú wa.”

Ka pipe ipin Mátíù 1

Wo Mátíù 1:23 ni o tọ