Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 9:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Iyọ̀ dára, ṣùgbọ́n tí ó bá sọ agbára adùn rẹ̀ nù, báwo ni ẹ ṣè lè padà mu un dùn? Ẹ ni iyọ̀ nínú ara yín, ki ẹ sì máa gbé ni àlàáfíà pẹ̀lú ara yín.”

Ka pipe ipin Máàkù 9

Wo Máàkù 9:50 ni o tọ