Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 9:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ọwọ́ rẹ bá mú ọ kọsẹ̀, gé e sọnù, ó sàn fún ọ kí o gbé títí ayé àìnípẹ̀kun pẹ̀lú ọwọ́ kan ju kí a gbé ọ sínú iná àjóòkú ọ̀run àpáàdì pẹ̀lú ọwọ́ méjèèjì.

Ka pipe ipin Máàkù 9

Wo Máàkù 9:43 ni o tọ