Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 9:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì sọ fún un pé, “Má ṣe dá irú ènìyàn bẹ́ẹ̀ dúró, nítorí kò sí ẹnìkan ti ó fi orúkọ mi ṣe iṣẹ́ ìyanu tí yóò tún lè máa sọ ohun búburú nípa mi.

Ka pipe ipin Máàkù 9

Wo Máàkù 9:39 ni o tọ