Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 9:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó jókòó, ó sì pè àwọn méjìlá náà, ó sọ fún wọn pé, “Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ ṣe ẹni ìṣáájú, òun ni yóò ṣe ẹni ìkẹyìn gbogbo wọn. Ó ní láti jẹ́ ìránṣẹ́ gbogbo ènìyàn.”

Ka pipe ipin Máàkù 9

Wo Máàkù 9:35 ni o tọ