Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 9:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun sì kígbe ńlá, ó sì nà án tàn tàn, ó sì jáde kúrò lára rẹ̀: ọmọ náà sì dàbí ẹni tí ó kú tó bẹ́ẹ̀ tí ọ̀pọ̀ ènìyàn ké wí pé, “Héè, ọmọ náà ti kú.”

Ka pipe ipin Máàkù 9

Wo Máàkù 9:26 ni o tọ