Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 8:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù yípadà, ó wo àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀. Ó sì wí fún Pétérù pẹ̀lú ìtara pé, “Kúrò lẹ́yìn mi Sátánì, nítorí ìwọ kò ro ohun tí Ọlọ́run bí kò ṣe ohun tí ènìyàn.”

Ka pipe ipin Máàkù 8

Wo Máàkù 8:33 ni o tọ