Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 8:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nisinsìn yìí, Jésù àti àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ kúrò ní Gálílì. Wọ́n sì jáde lọ sí àwọn abúlé ní agbègbè Ṣísáríà Fílípì. Bí wọ́n ti ń lọ lọ́nà, ó béèrè lọ́wọ́ wọn pé, “Ta ni àwọn ènìyàn rò wí pé mo jẹ́?”

Ka pipe ipin Máàkù 8

Wo Máàkù 8:27 ni o tọ