Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 8:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù fa ọkùnrin náà lọ́wọ́, ó sì mú un jáde lọ sí ẹ̀yin ìlú. Ó tu itọ́ sí i lójú. Ó sì gbé ọwọ́ rẹ̀ lé ojú náà. Ó sì bi í léèrè pé, “Ǹjẹ́ ìwọ lè rí ohunkóhun nísinsìn yìí?”

Ka pipe ipin Máàkù 8

Wo Máàkù 8:23 ni o tọ