Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 8:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù mọ ohun tí wọ́n sọ láàrin ara wọn, ó sì dá wọn lóhùn pé, “Èése ti ẹ̀yin fi ń ṣe àròyé pé ẹ̀yin kò mú búrẹ́dì lọ́wọ́? Ẹ̀yin kò kíyèsí i sì títí di ìsinyìí, ẹ kò sì ti mòye, àbí ọkàn yín le ni?

Ka pipe ipin Máàkù 8

Wo Máàkù 8:17 ni o tọ