Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 4:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó ku òun nìkan pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn méjìlá àti àwọn mìíràn, wọ́n bi í léérèè wí pé, “Kí ni ìtumọ̀ òwe rẹ̀?”

Ka pipe ipin Máàkù 4

Wo Máàkù 4:10 ni o tọ