Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lojú kan náà bí Jésù tí wòye nínú ọkàn rẹ̀ pé wọn ń gbèrò bẹ́ẹ̀ ní àárín ara wọn, ó wí fún wọn pé, “È é ṣe tí ẹ̀yìn fí ń ro nǹkan wọ̀nyí nínú ọkàn yín?

Ka pipe ipin Máàkù 2

Wo Máàkù 2:8 ni o tọ