Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 2:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láìpẹ́, ogunlọ́gọ̀ ènìyàn ti kún ilé tí ó dé sí tó bẹ́ẹ̀ tí inú ilé àti ẹ̀yìn ìlẹ̀kùn ní ìta kò gba ẹyọ ẹnìkan mọ́, ó sì wàásù ọ̀rọ̀ náà sí wọn.

Ka pipe ipin Máàkù 2

Wo Máàkù 2:2 ni o tọ