Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 2:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó si ṣe, bí ó sì ti jókòó tí oúnjẹ ni ilé Léfì, ọ̀pọ̀ àwọn agbowó òde àti ẹlẹ́ṣẹ̀ wá bá Jésù jókòó pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, nítorí ti wọn pọ̀ ti wọn tẹ̀lé e.

Ka pipe ipin Máàkù 2

Wo Máàkù 2:15 ni o tọ