Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 2:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lójúkan-náà, ọkùnrin náà fò sókè fún ayọ̀. Ó gbé ẹní rẹ̀. Ó sì jáde lọ lojú gbogbo wọn. Èyí sì ya gbogbo wọn lẹ́nu tóbẹ́ẹ̀ tí wọ́n sì yin Ọlọ́run lógo wí pé, “Àwa kò rí irú èyí rí!”

Ka pipe ipin Máàkù 2

Wo Máàkù 2:12 ni o tọ